Are You A Good Person?  (YORUBA VERSION)

(CLICK HERE FOR ENGLISH VERSION)

(CLICK HERE FOR FRENCH VERSION)

(CLICK HERE FOR ITALIAN VERSION)

 

SE ENI RERE NI O ?

 Oruko mi ni Jim Barbarossa, Ati wipe bi o sale fun mi ni aye mo fe ba o soro die nipa jije eni rere , se eni rere ni o ? Mo fe so die fun o nipa okunrin kan ninu bibeli ti ale pe ni emi rere, A o ma ka lati inu iwe [Ise awon Apostlic ori ikewa ] . Arakunrin Kan wa ni kesaria ti a npe ni koniwu, Egbe ogun ti a npe ni! Egbe ti itali ti o je adura Eni ti afi ase awon lile ni ogorun awon omo ogunle lowo.

Ese ikeji Emi ti o gba olorun gbo ti osi beru Olorun pelu gbogbo lle re, eni ti o nta ore aanu pupo. ti o si ngba adura  si Olorun ni gbog bo  igba nipa eyi Okunrin ti gbogbo idile re fi ara won ji ti won si beru olorun, Eni ti o ntore tabi ti nfuni ni ebun , ati okunrin ti o ngba adura si olorun ni igba gbogbo ati nipa awon nkan won yi  pelu adura re igbagbo  si olorun , ninu ese oro na tumo si gbigba adura si enikan ati Olorun alaaye, Nje Ole so pe okunrin rere ni eyi ?

Ese  iketa , Ori ninu iran ni nkan bi wakati kesan ojo ni bi deede agogo meta osan angeli olorun kan toowa osi wipe fun pe, konelin.

Ni deede agogo mefa yi tabi ni wakati kesan ojo , oje akoko adura , nipa be bi konelin se wa ninu adura , olorunran angeli kan si.

Atipe nigba ti o wo , eru ba osi sowipe , kini eyi Oluwa Ogba wipe eyi gbudo wa lati odo olorun tabi Oluwa owa so fun wipe , Angeli na so fun wipe , fun konelin , wipe itore re ati adura re ti wa si iranti ni iwaju olorun . Ni ona miran , kolehu Olorun ri ohun gbogbo ti o se. Olorun gbo adura re. Olorun ri ore re ati ebun re ti o nfun awon eniyan . won ti wa si oke bi ebo oorun didun niwaju olorun , olorun ti da o mo osi mo eni ti iwo nse.

Ese ikarun , Ni bayi ran eniyan kan ni si ibiyi  lo si joppa ki won si pe  simony wa, Eni ti apele re je peteru.

Bayi ni ona miran , Angeli yi to Okunrin rere  yi wa, konelin, osi so wipe olorun ti ranmi si o, Olorun mo eni ti o je, osi mo adura re ti o wa bi oke . Ori ebun ti o nfun awon eniyan , O mo wipe o dara , Eni aponle ni awujo re, Bayi olorun wa ranmi si o lati to arakunrin ni lo eni ti apele re nje peteru. To arakunrrin yi peteru lo, ti o ngbe ni odo Simoni Atana, Nipa be okunrin  yi yi o le so ohun ti o se fun o , ni ona miran o nso pe , konelin Otun ku . Okunrin rere ni o , Eni rere ni o Sugbon osi tunku, ati wipe olorun fe ki o ranse si arakunrin peteru yi , Nipa eyi yi o so awon nkan ti o ma se fun o.

Mo fe re koja lo si ori Ikankala iwe ise awon apostolic fun Itesiwaju , ese ikerinla , osi so wipe , Eni ti yi o so oro fun o bi a o ti gba o , iwo ati ara lle re gbogbo . Eyi ni ilana awon ohun ti peteru yi o so fun konelin nigba ti o ba wa si odo re. Eni ti yi o so ohun ti iwo ati ara lle re yi o fila  fun o . Nipa  eyi ni itesiwaju , Olorun ran angeli kan si koneliu lati ranse to peteru lo. Ati  wipe yi o wa so fun O ona ti iwo ati ara ile re yi o fi la , Ninu iwe mimo ti mo nse alabapin re pelu re, Olorun ran Angeli kan si arakunrin rere yi lati kin nilo, Angeli kan lati so  fun  arakunrin rere yi, lati kin nilo, Angeli kan lati so fun arakunrin rere yi , Ohun kan si tun ku ose pataki fun o lati si awari ohun  na .loni mo gbagbo wipe olorun nba o soro , ko tile ba o soro lati enu angeli , Sugbon o nba o soro nipa ero asoro magbesi , mo si ni igbagbo pe olorun ti gbe  da ohun elo kan lu bi gogowu nla ti nrako. Aye yi wa , ati eranko igbe ati ohun ti nranko , ati eye oju orun , ohun kan si fo si pe , peteru , ma pa ki osi ma je . Sugbon peteru dahun pe , beeko Oluwa , nitori emi ko je ohun eewo ati alaimo ri lai Ohun na si tun so fun leekeji , wipe ohun ti olorun bi ti enu , iwo mase pe ni eewo mo . Eyiyi  so be ni Erinmeta , asi gbe ohun elo na na pada lo si orun , bi ko ti yr peteru ninu ara re bi iran ti ori yi si, si woo , awon okunrin ti aran ti odo konelinu wa de, wo beere lle simoni won duro ni enu ona, won si beere lle simoni ti  anpe ni wo nibe . Bi peteru ti nronu iran naa, Emi si wi fun pe, Kiyesi awon okunrin meta nwa o, Nje dede sokale ki o bawon lo., masise ko ohun kohun nitori emi ni o ranwon .peteru si to awon okunrin na lo ti ati ransi lati odo koneliu , kiyesi , Emi ni eni ti e nwa . kilo sele lati ibo ni eti wa.

Ni ona miran o nso wipe kini ewa se ni Ihin ? Kini efe fun mi ? kini efe ki nse fun yin ? Won si wipe koneliu Balogun orun , okunrin olooto ati eni ti o beru olorun , ti o si ni ihinrere lodo gbogbo awon juu, Ohun ni ati odo olorun wa iko nipase angeli mim , ki o ranse si o ki iwo wa sile re, lati gbo oro olorun  lenu re.

Mo ro wipe ohun alagbara kan wa, Olorun ki n wulo lati owo angeli , mimo , okunrin rere yi , Okunrin ti o ni iberu Olorun daradara yi. Ati le ti so ni Ihin pe eni ti o ni eri rere larin awon eniyan. Okunrin yin je eni ti oni ase lori awo jagunjagun . Okunrin ti gbogbo eniyan nfi ola fun okunrin ti awon eniyan ngbe oju soke si, Okunrin to o nfifun awon alaini . Fi o ntore , olorun  kin ero yi le o lowo , mo si ni igbagbo pe olorun fe ki o mo loni jije okunrin rere , tabi obinrin rere, tabi eni rere tabi eda eniyan rere ko iti to . Olorun fe ki o mo pe ogbudo di eni igbala , Gege bi arakunrin koneliu yi , boya otile ti nfi ore fun awon talaka .

Boya otile ti nbo awon otosi . Boya otile ti n nfun ijo olorun , Boya otile ti nfun awon eso re gbogbo .

Boya otile ti nlo si ile ijosin ni ojo isimi , Boya otile ni ipo ti o dara larin awujo , Awon eniyan feran re awon eniyan nbowo fun o , Odara be, bi ti ara kunrin koneliu yi, Olorun nso fun o loni pe ko iti to . Osi “tun kun si” Be gege bi ti koneliu , o nfe ki o se awari oni lati ri igbala.

 

Eje ki a tesiwaju ni Ori Keje , ki a si ri ohun ti koneliu se. Nigba ti angeli si nso oro na fun koneliu o ya , o si pe meji ninu awon ti o nse iranse fun  nile re ninu awon jagunjagun ti ati yan ti o nse ise lodo re nigba gbogbo . Ati nigba ti o si so awon nkan won yi fun won osi ranwon si jappa.

Ati nigba ti angeli na si nkin koneliu nilo, kotile jiyan , ko fi akoko sofo , sugbon ope ikan ninu iranse ti ati ya soto , ope jagujagu re oran won ki wo ki o lo si jappa , lati se ohun ti olorun so fun lati se. Ati iwo loni, O tun nilo lati fi akoko sofo, sugbon o gbudo se awari ohun ti olorun fe ki  o mo , Ati Ona niyi fun o lati ri igbala.

Antesiwaju ni ese kesan , Ati ni ojo keji , Bi won ti nba ona irin ajo won lo ti o kun  die ki won de ilu na peteru goke aja lo gbadura lo akoko wakati kefa ojo, Ebi si ti npa gan, iba si jeun , sugbon nigba ti ati seto , osubu sinu iran kan, ori orun  si sile , asi nilo osi ran angeli kan si , koneliu mo ri ohun gbogbo ti iwo nse , mo mo eni ti iwo nse .Sugbon oro kan wa ti o gbudo gba lati enu arakunrin ni ti a pe oruko re ni simoni , Osi ni lati ranse si.

Owa yani lenu loni , se olorun tile tun nkin awon eniyan nilo loni? Mo si gbagbo pe osi nse be , mo gbagbo pe ikan lara aawon ona ti olorun fi nkilo fun awon eniyan re loni ni nipa kasefi ibawi soro , osi nso si keseti yi osi nfi si owo awon eni rere , eni ti o ni iberu rere fun olorun , si awon ti won ngbadura si olorun , ati awon ti won tile nfifun , ati awon ti won tile nlo si lle ijosin , owa nso bayi ninu ise re yi , Mo kilo fun o , awon ohun ti osi nse ni koiti to, Osi ni lati se awari ohun ti o ku o ku ni Ese ketala logun, Nigba na ni o pe won wole osi mu won wonu lle lo, osi di ijokeji peteru bawon lo ati awon kan ninu awon arakunrin ni joppa baa lo . Osi di ijo keta won wo kesarea koneliu si ti nreti won , Osi ti pe awon ibatan , ati awon ore ti o wa nitosi jo.

Koneliu ko ranse si simoni nikan sugbon otun pe awon ti o sun mo , ara llere , awon ore re, ati awon ti o nfi owo fun pe ki gbogbo won wa ki won wa gbo ohun ti arakunrin yi fe so , lati gba ohun ti olorun fe ki o gbo osi mo pe eyi je apere rere fun emi ati iwo pelu , pe ami lati ni isiniye gbo lati enu awon ti olorun  ti ran . Ti aani lati gbo funra wa nikan , sugbon ani lati ni okan kan pe afe ki molebi wa, ati awon ore wa ati awon ti o wo  wa ki won le gbo bakan na.

Sugbon bi peteru ti wole koneliu sure pade re, o wole fun , osi fori bale fun. Sugbon peteru gbe dide, oso wipe dide eniyan ni emi funra mi. Bi osi ti nba soro, o wole , o si ba awon eniyan pupo ti won pejo . Osi wi fun won pe, Eyin mo bi ko ti ye fun eni ti nse juu, lati ba eni ti nse ara lle miran kegbe , Oun ati too wa, sugbon olorun ti fi han mi pe , ki emi ki oma se pe enikan ni eewo tabi alaimo , Nipa eyi , nitori na ni mo se wa si odo yin laijiyan niwon igba ti ati ran mi, nje mo beere nitori kini eyi se ranse simi.

 

A ran mi,

Bayi , simoni so gbangba pe “Nipa temi , mo ti pinu pe mi o ni si nibe .

Nipa temi , ma je ki temi yato lati farapamo kuro lodo yin . Sugbon olorun wipe mo setan lati to yin wa.

Koneliu wipe , ojo merin seyin , mo wa ninu awe titi di wakati ati wakati kesan ojo , mo gbadura ninu ile mi si, kiyesi arakunrin kan duro lokere pelu o wo aso ala.

Bakannaa, koneliiu pin , “ O gbadura . o wa olorun . olorun si ran Angeli (Ogun – orun ) si mi.

Ese Ikokanlelogbon , o wipe koneliu “Adura re ti gba , ore se si goke fun iranti niwaju olorun . Ranse lo si Joppa , ki o si pe simoni ti apele re nje peteru , o wo ni ile simoni Atana ti o wa leti okun , ohun ni eni naa ti yoo ba o soro.

Lotito oun ti o sele nihinyi ni pe koneliu yara goke lo o si tun wi ewe pe , “ Olorun ran angeli re si mi , Angeli naa wi fun mi pe olorun gbo adurare. Olorun ri pe mo san ore olorun ri pe mo san Ebun .Ati wipe gbogbo nkan won yi wa siwaju re fun iranti , o kami si o mo iru eniyan ti o je . Eyi nipe olorun ni o ran simoni nitori pe arakunrin naa ni lati to om wa, ati lati sajopin oro olorun pelu re.

Ese Iketalelogbon, Nitorinaa ni mo si ti ranse si o lojukanna , iwo si seun ti o fi wa. Gbogbo wa pe niwaju olorun nisisiyi lati gbo ohun gbogbo ti a palase fun o lati odo olorun wa.

Ni ona miran, o wipe “ omo mo pe oun nso ti olorun mo mo pe olorun ni o mu o wa sihinyi. A ti korajopo si ibi yi , A fe gbo ohun ti olorun fe tipase re bawa so, “

Ni ese Ikerinlelogbon, peteru si ya enu re , o si wipe , nitoto mo woye pe olorun ki sojusaju eniyan . Sugbon ni gbogbo orile – ede , eniti o ba beru re, ti o si nsise ododo , eni itewogba no lodo re oro ti olorun ran si awon omo Israeli , nigbati  o nwasu alafia nipa jesu Kristi , ohun ni oluwa oun gbogbo . Eyin naa mo oro naa ti a ti kede re yika gbogbo Judea , ti a bere si lati Galili wa lehin ti johannu Baptismu wasu re. Ani jesu ti Nasareti , bi olorun ti da Emi –mimo ati agbara lee lori , eniti o nkiri se ore , nse dida ara gbogbo awon ti esu npon loju, nitori olorun wa pelu Re. Awa si ni eleri gbogbo ohun ti o se, ni ile awon ju ati ni Jerusalem , eniti nwon pa, ti nwon si fi gbeko sori igi on ni olorun jinde ni ojo keta, o si fi han gbangba . ki ise fun gbogbo eniyan bikose fun awon eleri ti a ti owo olorun yan tele , fun awa, ti a ba je , ti a si baa mu lehin igbati o jinde kuro ninu oku.

 

Ninu oro miran, o wipe, “mo nibo nigbati oinde kuro ninu oku, mo ti baa je po mo tile joko pelu Re muu mo ri jesu ti Nasareti mo je eleri jesu ti Nasareti”.

Ni itesiwaju ni ese ikejilelogoji, o si pase fun wa lati waasu fun awon eniyan, ati lati jeri pe, on lia ti owo olorun yan lati se idajo aaye ati oku ohun ni gbogbo awon woli jeri si pe nipa oruko re ni enikeni ti o ba gbaagbo, yio imukuro ese gba.

Eleyi Ni oun ti olorun fe ki konehu o gbo. Olorun nfe ki konehu mo wipe nipase jesu krist ati wipe ohn ti jesu se lori igi Agbelebu lo mu ki konehiu ri ojurere lodoolorun. O salaye gbangba pe, “konehiu, mo mo pe eni rere ni o gege bi iwon re pe sugbon eleyi ko to rara. Mo mo pe ohun gbadura si mi sugbon eleyi to ko rara. Momo pe ounse ififunni awon talaka sugbon eleji ko to rara” sugbon laasi

Jesu krist , laisi gbaa ohun ti jessu se nigbati o kuu lori igi agbelebu gbo ati ajinde kuro ninu iboji Re, Laisi eleyi  , ko si idariji fun ese eniyan .

Bibeli je ko yewa ninu ise awon Apostwl ori kerin ese ikejila, Nitori ko si igbala lodo elomiran Beni ko si oruko miran labe orun ti a fi fun wa lati gbawala.

Ninu oro miran, nipase jesu nikan nti a le mo olorun Lori nti ale lo si ile-isin. Ni a le duro bi omo –ibile gege bi ofin ile ti ri sugbon nipa oruko jesu jesu ni a le gba imukuro Ese ati igbala Gege bi Arakunrin  konehiu olorun ran ikilo naa ikilo /ipenija si wa lori nipase oro ti a ugbo yii. Ipenija /ikilo naa ni wipe, o gbodo di Atunbi. O gbodo ni Ibasepo ti oi gunrege/yaaunti pelu jesu kristi  Didara olorun mo nikan ko to. Gbigbadura si olorun nikan koto. Ifuuni nikan ko to ogbodo ni ibasepo niti o gunrege nipase omo nipa jesu kristi .Eleyi ni ona si odo.

Ona si odo Baba wa nipase omo boya o le so funra re gege bi o ti fetibale si ero yii.” Bawo ni eleyi se le rise ? mo ti je eni rere ni gbogbo ojo aye mi mo je eni giga ninu ijo mo ma nlo si ile ijosin ni gbogbo igba mo ma ngbadura nigbagbogbo . Mo ma seranlowo nigbagbogbo  mo ma njade sita nigbagbogbo lati se rere fun awon eniyan mo je eni rere “. O dara , mo woye pe be loye ki ibere mi ri , Nipa osunwon wo ni a o fi dawalejo boya tabi beeko a je eni rere?” Nje a dara wa lejo nipa osunwon ti aye kinni erogba awon ti won wa layika wa, kini ofin ile so nipa re ?  O mo pe okunrin ti a npe oruko re ni koneliu ti a nsoro nipa re o je  enikan to ni apere rere ni awujo o tun je enikan ti o ni iteriba ti ki sojusaju ni awujo o je enikan ti a fun lase lori awon ogorun omo – ogun .ohun ni eni – naa ti o se idajo nipase Aye , ti o si farahan ni ona to yanranti .Sugbon ranti , olorun ran ogun  orun (Angeli) sii, o si kilo fun pe o san fun ki owa ohun ti o sonu . Bakanaa, atipe eyi je ara ibatan jesu Kristi.

Ohun ti a ni lati wo fun iwon wa  pelu olorun ni ofin mewa , mo fe daradara ninu iwe Eksodu ori ogun .

Ofin Ikinni , ma sin olorun miran , ofin Ikeji , ma se gbe Ere kere . se o ti gbe ise ona gba ju olorun lo ninu aye re ? Bi o ba ti seleyi , o ti ru okan ninu ofin olorun.

Ofin Iketa , ma se pe oruko olorun re lasan , tabi ki o fi bura . se o ma lo oruko olorun lati fi omonikeji re? Oruko olorun gbodo je eleyi ti a nfi fiyin fun lati sin olorun. Oruko re gbodo ni owo / iteriba ninu.

Ofin Ikerin, ya ojo isinmi si mimo. Ni ojo naa, e ko gbodo sise kankan se o mo lo ojo kan soto lati wa owo oto ni ojo isinmi ?.

Ofin Ikarun, Bowo fun Baba ati iya re .

Eleyi ni a nso nipa re nigbati a wa ni ipere / omode . Nje o bowo fun Baba ati Iya re.

Ofin Ikefa, Iwo ko gbodo paniyan.

Jesu oluwa salaye lekunrere lori re ninu iwe (mattew 5 – 22 ) , o wipe , ti o ba ti binu , ow a ninu Ewu idajo se o ni ibinu ninu okan re si enikeji re?

Ofin Ikeje , Iwo k gbodo se pansaga

Jesu oluwa tenumo bakannaa, o so ninu (mattew 5 – 28 ) , Enikeni ti o ba wo obinrin kan lati se ifekufe sii ni oju re, o ti ba se pansaga tan ni okan re. Se o mo wo ju obinrin , se o mo wo oju elomiran se o mo wo eniyan lati se ifekufe si lokan re.

Ofin Ikejo,Iwo ko gbodo jale.

Se o ti mu nkan ri ?  ko tumosi bi o ti tobito tabi bi o ti kere to , ko da lori bi owo re ti po to , tabi bi o ti gbiye to. Ibere naa ni wipe, se o ti ji nkan ri ? Bi o ba ti gbe nkan , o ti ru ofin olorun o ti ba pkan ninu ofin je , kinni a npe eni naa to o jale ? ole bi o ba ti jale, o le ni o .

Ofin Ikesan, Iwo ko gbodo paro.

Se o ti paro? Ko tunmosi pe, boya iro nla tabi kekere , iro ni iro nje , se o ti se otito ? se a o kan mo so itan lasan bi ? se o kan ma nfe ka so ohun kan ti yoo sanfani fun o ti yoo so awon iyoku nu? Se o ti ma paro ? Bi o ba ri be, kini o se okunfa re? Ti o so di oniro gan-an.

Ofin Kewa, Iwo ko gbodo se ilara.

Iwo ko gbodo se ilara ile aladugbo re , tabi oko ayokele re tabi obele re, tabi ibugbe re tabi ikan elo re tabi aya re tabi ohun ini re . o ti se ilara ohun ti awon eniyan ni tele bi ? o mo ni ikorita yii o le ma roo.

Sugbon, Emi o le wa pelu ofin wonyi tani o le gbe tabi wa pelu ofin wonyi?

O ti wa, tabi o ti gbe nipa ofin wonyi ? nje o ti gbe pelu ofin wonni? Nje o mo bi iwo ba ti ru okan ninu won o je pe o ti se si olorun ? E je ki a wo iwe ifihan lati ri isele ti o sele si awon to ru ofin tabi ilana olorun ninu iwe ifihan ori kokanlelogun bere lati ese ikarun (ifihan 21 – 5 ). Oro olorun wipe , eniti o joko lori ite ni si wipe kiyesi mo so ohun gbogbo di otun , o si wi fun mi pe kowe re, nitori oro wonyi ododo ati otito ni nwon o pari Emi ni ipinle ati opin Emi o si fi omi fun eniti o ngbe gbe lati orisun omi iye lo fe .

Gbogbo eniti o segun ni yi o jogun ibukun wonyi , Emi yi o je olorun re yi o si je omo mi awon ti ongbe gbe ti yio jogun orisun omi iye ,eyi ni awon to kope olorun ti won si gba jesu Kristi ni olugbala won .Ebi yi ni Jesu kristi.

Gbogbo eniti o segun ni aye, yi o jogun ibukun woni, Emi yi o si olorun na yi o si je omo ni.

Eyi ni o duro de awon to kigbe pe olorun won si gba jesu ni olugbala won.

O tesiwaju ni ese kejo (verse 8 ). O so ohun ti yi o sele si awon to re ilana olorun koja, To ru ofin re.

Sugbon awon ojo ti won ko lati tele mi, awon ti won ko gba jesu kristi awon ti won je alaisoto si mi, ati awon oniwa ibaje , ati apaniyan , ati olusebuburu ati awon ti won se pelu emi buburu, ati aborisa ati alasoto gbogbo, iparun wa ninu adagun ma ti fi sufuru jo ,Eyi ti n se iku keji.

Ibi ti awon opuro nlo niyi, o le ranti  a so nipa ofin opuro ni o . Bi o ba laini jesu Kristi , o ti ni eto lati lo okun apadi, laisi jesu Kristi ko si ireti , kosese o le da pa ofin yi mo fun ara re. Ko rorun , o ko le se , jesu Kristi nikan lo le pa ofin wonyi mo funrare , Ranti pe jesu wa lati mu ofin se fun o lati gbe pelu ofin wonyi, o nilo jesu Kristi nipa idariji ki a le mu ese wonyi kuro ati lati mu kro nioa eje re. Ki o ba le ri itura ati ojurere lodo oluwa , ki o si tun wa  lorun pelu re nipase jesu Kristi nikan ni.

Ko ni se pelu pe o ti nto ile ijosin fun odun mewa ogun odun, ogbon odun, ko ni se pelu pe o dara lojin awon aladugbo re, ko ni se pelu pe o nse itoju awon ti o yioka, fi fi fun alaini.

Bi o ku ba ti se ohun ti peteru so fun konnin iba lara lati se atunse, eniti ti jesu krist gbala, bi o ka ba ti se ohun kan yi awon ohun gbogbo to ku fi fi akoko sofo ni Nitori ibi ti konimu iba pan tabi  je opin re ni o ma  pani si laisi jesu krist ore mi eyi ni orun apadi

Johanu 14 ese 6, jesu wi fun won pe, emi ni ona otito ati iye, ko si eni ti o le wa sodo  bikose nipase mi.Ko wipe kosi eni to le sodo Baba nipa ise rere tabi loto si ile ijosin tabi fififun alaini O wipe mi, Nipa Jesu, ouu ona otito ati iye.

Kosi ona miran sodo Baba  bikose ko di atunbi lati pase Jesu Krist, Johaun 3;16 oro olorun wipe, olorun fe araye to beee ge, ti ofi omo bibi re kan soso fun, pe enikeni ti o ba gbagbo ko ma segbe subon ki ole ni iye ainipekun.

Ni ona miran, enikeni ti yionba yan lati gba Jesu Krist gbo koni segbe sugbon yio ni iye ti o dara. Ko wipe awon to se eyi tabi iyen, Kowi ohunkohun ju, bi eniyan ba fe iye ainipekun, oun tesiwaju in ese 17.

Nitoripe olorun Koran omo re saye lati da araye lejo, bikose lati gba arayela. Eni to ba gbagbo akoni da lebi, nitori ko gbagbo ninu omo kan soso ti olorun.

 

Awon ohun ti nso wipe, ti ma yan ti won ko gbagbo ninu jesuti

jabinatigbogboawon ti won saigboran  si ofin olorun, paapaa julo, ofin

mewa. Nigbati won re duro niwaju olorun ni ojo idajo. Iwa buburu awon ti won re

ofin olorun koja, won  yoo gba idalebi lati odo olorun onidajo ododo olorun yoo

dawon lejo,eyi ni orun Apadi olorun ki yoo da won lejo.awon gan-an darawonlejo nipase pe won ko lati gbagbo ninu oruko jesu krist. Se o ti yan lati wa ni

alaigbagbo, won ko gbaagbo ninu oruko jesuj krist ?Nje ni ipin re se ijoba

olorun ni tabi orun Apadi. Ewo ni ipin re .

Boya bi o ti ngbo oro  yii ,o nnwi ninu nokan re, “oh ,bi o ba sepe mo mo tele  iba ti yipada mo ti sapa mi sugbon mo ri gba ngba ninu oro olorun pe igbiyanju mi koto,wipe mi o kunjun osuwan niwaju olorun nitorinaa ni mko se re ofin re koja fe yipada.kini  ki emi ki o se?

O dara, bakanna, je ki a je  ro olorun wo Ninu iwe romu ori kewa, ese kesan, babili wipe bi o ba le fenu re  jewo jesu ni oluwa, ti iwo si  ngbagbo ni okan re  pe, olorun ji dide kuro nimum oku, a o gba ola

Eyi ni nkan ti o ni lat se o ni lati gbagbo ki osi jewo jesu krist gege bi olugbala re

Ni ese ikewa, okan  ni eniyan fi ngbaagbo si ododo, enu ni ajewo si igbala

Bi o ba fe deni igbala o ni lati gbagbo ninu okan re o ni lati jewo ni enu re sugbon o le so pe “kinni mo le fi jewo” o nii lati jewo pe elese  ni o je

Bibeli wipe , gbogbo eniyan ni o sa  tise ti won ti kuna ogo olorun o ni lati jewo pe elese ni o, o ni lati seejeri re Beeni “mo ti ru ofin o,orun :”mo je oruro. O puro no mi mo mu nkan elomiran. mo je ole ole mo se pansaga ni okan nipa wiwo obinrin loju nmo ti bura, loli oruko olorun lasan . mi o teriba fun awon baba ati iya mi rara . mi o pa ojo isinmi mo mo ti ru ofin lopolopo”.

Ni itesiwaju ni ori ikokanla, nitori iwe mimo wipe enikeni to ba gbagbo oju ki yoo ti ti ona miran enikeni ti o gbagbo ninu oruko jesu ko le kule lailai.

Nitori ko si iyato laarin juu ati  Giriki  nitori oluwa kanna loluwa gbogbo won o so po ni oro fun gbogbo awon ti nkepe nitori enikeni to ba sa pe oruko oluwa ni a o gbala.Enikeni ti o ba jewo ese re itumo re ninu okan ati wipe kigbesoke ki o pe oruko olorun , ni oruko jesu Kristi a o si gba ola ore mi opolopo eniyan gbogbo kaakiri agbaye ni won gbagbo pe  awon ni ibugbe ni orun . Ti won si gbagbo pe awon  se rere daradara ti o lo niwaju olorun yoo mu ki won ni ibugbe ni orun won ro lokan won pe awon je emi rere, won se rere fun omo ni keji won lowo seranlowo fun opolopo eniyan won ya aladugbo won lowo lasiko aini re , won sise ninu ile arakunrin won lasiko to nilo iranlowo won .

Opolopo awon eniyan ni won nworawon bi eni ododo , ti o si nsise to dangajia, ati wipe won ro lokan ara won pe ojo gbogbo yoo fun won lanfani lati pelu olorun ni orun.

A leri gbangba loni pe, nipase oro olorun , ni olorun wipe , rara ko le rise “ olorun naa wipe , koneliu , mo kilo fun o , bee mo ri gbogbo ise rere ati awonnkan ribiribi ti o se , mo kilo fun o pe, o dara ki o wa  nkan ti o sonu . Nigbati o ran okunrin naa peteru , peteru so fun awon ikorita ti o sofo tori ko ni imo nipa jesu oluwa , omo olorun alaye , wa si aye yi ,  o wa gege bi eniyan o ku lori igi – Agbelebu , o jinde kuro ninu oku , bi iwo ba gbagbo ninu okan re ti o si jewo re, a o gba ola .

Nitorinaa, mo roo loni , ma se faye gba emi igbaraga lati dena re lati jewo jesu loluwa ati olugbala loni . ma se je ki emi naa dide duro ninu re ki o si wipe , “ mo to se daradara naa. Emi ki se elese mo gbon loju olorun “ .

Kiyesi , mo se fun o lonii , bi o ko ba bere lowo olorun fun idariji, ki o si pe jesu kristi ki o wa sinu okan re, bi o ko ba waaye fun ironupiwada , o ko ti kunjun osunwon rara. Awon eniyan rere ko ni yoo lo si orun. Awon eni idurosinsin pelu olorun ni yoo goke lo si orun .Ona kansoso  ti o le gba lati kuujun osunwon pelu olorun wa nipase jesu Kristi .

Bi o ba fe mo dajudaju boya o ni ibugbe ni ijoba olorun ni orun a si ti dari ese re jin o , mo fe.

Iwo gba adura pelu mi bayi

Olorun olufe, elese ninu . Mo ti ba ofin re je mo ti jale mo ti paro mo ti ba ofin re je. Olrun mo njewo awon nkan wonyi loni fun ohun ti won je . Ese olorun mo wa kegbe fun aanu re,  mo si nbebe pe  kii o darijimi ,mo gbagbo wipe oran omo re,  jesu krist ati wipe jesu kan lori agbelebu osi tun jinde kuro ninu oku , ati wipe oti ru ese mi lo , konleri aanu gba lati odo re,  olorun sanu fun mi dari ese ni jimi , jesu wasinu, okan mi ki osi ma dari mi iwonba ti ojo aye mi  kun, mo fi sile fun o lori, ma si bere si ka Bibeli, ma si ma losi ile ijosin .

Ma si ma josin pelu awon onigbagbo , ma si tun mase alabapin igbagbo mi pelu awon miran ti mo ba lee ri basoro olrun sanu fun mi Emi elese.

Bi oba ti ngba adura yi bayi iwo na ko wa lasan oti di eni rere , sugbon o je eni ti o di ti olorun nipase jesu krist. A ki o kaabo si idile olorun mo lero wipe oole ma bawa soro ni ipele ipele.Afe  ma gbo lati odo re, mo fe ki o mo wipe olorun tuntun ti gbbodu ma sele ninu igbe aye re lati akoko yi lo ,ogbado ma ni imo yato ati wipe ma se ohun ti o yato bayi.

A gbudo ri eso igbagbo ati wipe lara awon eso yi ti yio maa to  awon miran si odo jesu kristi.Ranti , Bibeli wipe o gbudo jewo lenu ara re to awon ti o mo pe o je onigbagbo nin jesu krist lo ki osi nse abapin pelu re ohun ti oti se. Je ki won pe oti be olorun ko I je olugbala.

Mo si tun nsofun o pe o ma fi towa leti mi stepby step astepbt-step. Arg. Oro yi ti o ngbo oje ara oun elo ipesse oun ti a agbe kale lati lo bi eleri lati yi eniyan pada , bi o ba fe ipa keji pe tabi kowe siwa.

Gege bi isise  akoko ni pinpin igbagbo mu ero yi fi fun elomiran ti o wulo fun lati mo jesu kristi , Aye wa lati fun te mase je ki igba to ba wun o yi o dara fun o bi o ba se eyi tan mu lo fun eloomiran , to o nilo jesu krist , ki olorun bukun o ,a feran re ni  igbe aye rere ati asiko nla pelu olorun ni orun.